Download Chief I.K. Dairo & His Blue Spots Band - Okan Mi Yo Ninu Oluwa / Okan Mi Yin Oba Orun (Audio) free MP3
Song: Chief I.K. Dairo & His Blue Spots Band - Okan Mi Yo Ninu Oluwa / Okan Mi Yin Oba Orun (Audio)
Description: 60's Juju Classic from the Late I.K. Dairo
"Okan Mi Yo Ninu Oluwa" (My Heart Rejoices in the Lord.)
Yoruba Lyric:
Okan mi nyo ninu Oluwa 'tori o je iye fun mi (2 times)
Ohun re dun pupo lati gbo, adun ni lati r'oju re
Chorus:
Emi nyo ninu re, emi nyo ninu Re
Gba gbogbo lo fi ayo kun okan mi
'Tori emi nyo n'nu re.
O ti pe k'in to mo o, 'gbati mo rin jina s'agbo
O gbe mi wa si'le l'apa re, nibiti papa tutu wa
repeat chorus
Ire at'anu re yi mi ka, or'ofe re nsan bi odo
Emi re nto, o si nse 'tunu, o mba mi lo si 'bikibi
repeat chorus.
___________________
'Okan Mi Yin Oba Orun'( My Heart Praises the King of Heaven.)
Yoruba Lyric:
Okan mi yin oba orun, ko'rin didun b'e nti lo
'Wo ta wosan, t'a dariji, tal'aba ma yin bi re ?
Yin Oluwa, yin Oluwa, yin oba ainipekun (2 times)
_____________________
Much respect to MOOS of GLOBAL GROOVERS for the vinyl rip and audio file of this masterpiece.
Visit MOOS at:
http://globalgroovers.blogspot.com/
Tags: dairo, taxi, driver, ijo, olomo, juju, highlife, yourba, ijebu, ijesha, eko, lagos, naija, nigeria, okan, mi, yo, ninu, oluwa, oba, orun
Duration: 05:47
Download - 
Listen - 
Watch Video - 
|
|
Related Songs
|